Sáàmù 9:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èmi o yìn ọ, Olúwa, pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi;Èmi o sọ ti ìyanu Rẹ gbogbo.

2. Inú mi yóò dùn èmi yóò sì yọ̀ nínú Rẹ;Èmi o kọrin ìyìn sí orúkọ Rẹ, Ìwọ Ọ̀gá-Ògo jùlọ.

3. Àwọn ọ̀ta mi pẹ̀yìndà;Wọ́n kọsẹ̀ wọn sì ṣègbé níwájú Rẹ.

Sáàmù 9