Sáàmù 9:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú mi yóò dùn èmi yóò sì yọ̀ nínú Rẹ;Èmi o kọrin ìyìn sí orúkọ Rẹ, Ìwọ Ọ̀gá-Ògo jùlọ.

Sáàmù 9

Sáàmù 9:1-10