6. Ìwọ mu-un jọba lórí gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ Rẹ;ìwọ si fi ohun gbogbo sí abẹ́ ẹsẹ̀ Rẹ̀:
7. gbogbo ọ̀wọ́ ẹran àti agbo ẹran,àti ẹranko ìgbẹ́,
8. ẹyẹ ojú ọrun,àti ẹja inú òkun,àti ohun tí ń wẹ nínú ipa òkun.
9. Olúwa, Olúwa wa,Orúkọ Rẹ̀ ti ní ìyìn tó ní gbogbo ayé!