Sáàmù 7:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó fi ọpẹ́ fún Olúwa nítorí òdodo Rẹ̀Èmi ó kọrin ìyìn sí Olúwa tí ó ga jùlọ.

Sáàmù 7

Sáàmù 7:13-17