Sáàmù 8:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ mu-un jọba lórí gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ Rẹ;ìwọ si fi ohun gbogbo sí abẹ́ ẹsẹ̀ Rẹ̀:

Sáàmù 8

Sáàmù 8:1-9