Sáàmù 8:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa, Olúwa wa,orúkọ Rẹ̀ ti tó tóbi tó ní gbogbo àyé!Ìwọ ti gbé ògo Rẹ̀ gaju àwọn ọ̀run lọ.

Sáàmù 8

Sáàmù 8:1-9