Sáàmù 8:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ẹnu ọmọ ọwọ́ àti ọmọ ọmúni o ti yan ìyìnnítorí àwọn ọ̀ta Rẹ,láti pa àwọn ọ̀ta àti àwọn olùgbẹ̀san lẹ́nu mọ́.

Sáàmù 8

Sáàmù 8:1-9