Ṣùgbọ́n ní ti èmi, ó dára láti súnmọ́ Ọlọ́runÈmi ti fi Olúwa Ọlọ́run ṣe ààbò mi;Kí èmi ó lè máa sọ̀rọ̀ iṣẹ́ Rẹ.