Sáàmù 74:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run, èéṣe tí ìwọ fi kọ̀ wá sílẹ̀ títí láé?Èéṣe tí ìbínú Rẹ̀ fi dìde sí àwọn àgùntàn pápá Rẹ?

Sáàmù 74

Sáàmù 74:1-9