Sáàmù 72:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ìkúnwọ́ ọkà wà lórí ilẹ̀;ní orí òkè ni kí ó máa dàgbàkí èso Rẹ̀ kí o gbilẹ̀ bí ti Lébánónìyóò máa gbá yìn-ìn bí koríko ilẹ̀.

Sáàmù 72

Sáàmù 72:11-20