Sáàmù 72:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí orúkọ Rẹ̀ kí o wà títí láé;orúkọ Rẹ̀ yóò máa gbilẹ̀ níwọn bí òòrùn yóò ti pẹ́ tó;wọn ó sì máa bùkún fún ara wọn nipaṣẹ̀ Rẹ.Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ní yóò máa pè mí ní alábùkún fún.

Sáàmù 72

Sáàmù 72:13-19