Sáàmù 72:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì yè pẹ́!A ó sì fún un ní wúrà Ṣébà.Àwọn ènìyàn yóò sì máa gbàdúrà fún-un nígbà gbogbokí a sì bùkún fún-un lójojúmọ́.

Sáàmù 72

Sáàmù 72:9-20