Ṣíbẹ̀ mo jẹ́ òtòsì, mo sì jẹ́ aláìní;wa kánkán sí ọ̀dọ̀ mi, Ọlọ́run.Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ àti olùtúsílẹ̀ mi; Olúwa, má ṣe dúró pẹ́.