Sáàmù 70:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n kí àwọn tí o ń wà ọ ó máa yọ̀kí inú wọn kí ó sì máa dùn nípa Rẹ,kí àwọn tí ó ń fẹ́ ìgbàlà Rẹ máa wí pé,“Jẹ́ kí a gbé Ọlọ́run ga!”

Sáàmù 70

Sáàmù 70:2-5