Sáàmù 59:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá à mi, Ọlọ́run;dáàbò bò mí kúrò lọ́dọ̀ àwọn tí ó dìde sí mi.

Sáàmù 59

Sáàmù 59:1-4