Sáàmù 58:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ènìyàn yóò wí pé,“lóòtọ́ èrè àwọn ń bẹ fún olódodo;lóòtọ́ òun ni Ọlọ́run tí ń ṣe ìdájọ́ ní ayé.”

Sáàmù 58

Sáàmù 58:1-11