Sáàmù 59:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníṣẹ́ búburúkí o sì gbà mí lọ́wọ́ àwọn ènìyàn tí ń pòǹgbẹ ẹ̀jẹ̀.

Sáàmù 59

Sáàmù 59:1-11