Sáàmù 56:10-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Nínú Ọlọ́run, ẹni tí mo yìn ọ̀rọ̀ Rẹ̀nínú Olúwa, ẹni tí mo yìn ọ̀rọ̀ Rẹ̀:

11. Nínú Ọlọ́run ni ìgbẹ́kẹ̀lé mi:ẹ̀rù kì yóò bà míkí ni ènìyàn le ṣe sí mi?

12. Mo jẹ́ ẹ̀jẹ́ lábẹ́ Rẹ Ọlọ́run:èmi o mú ìyìn mi wá fún ọ.

13. Nítorí ìwọ tí gbà mí lọ́wọ́ ikúàti ẹsẹ̀ mi lọ́wọ́ ìṣubú,kí èmí lè máa rìn níwájú Ọlọ́runní ìmọ́lẹ̀ àwọn alààyè.

Sáàmù 56