Ṣùgbọ́n ìwọ, Ọlọ́run, ni yóò mu àwọn ọ̀tá miwá sí ihò ìparun;Àwọn ẹni tí òǹgbẹ ẹ̀jẹ̀ ń gbẹ àti ẹni ẹ̀tànkì yóò gbé ààbọ̀ ọjọ́ wọn.Ṣùgbọ́n fún èmi, èmi gbẹ́kẹ̀lé ọ.