Ṣàánú fún mi, Ọlọ́run, ṣàánú fún mi,nítorí nínú Rẹ ni ààbò ọkàn mí wà.Èmi o fi ààbò mí síbi ìyẹ́ apá Rẹtítí tí ewu yóò fi kọjá lọ.