Sáàmù 55:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbé ẹrù Rẹ lọ sí ọ̀dọ̀ Olúwayóò sì mú ọ dúró;òun kò ní jẹ́ kí olódodo ṣubú.

Sáàmù 55

Sáàmù 55:17-23