Sáàmù 53:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Asiwèrè wí ní ọkàn Rẹ̀ pé:“Ọlọ́run kò sí.”Wọ́n bàjẹ́, gbogbo ọ̀nà wọn sì burú;kò sì sí ẹnìkan tí ń ṣe rere.

Sáàmù 53

Sáàmù 53:1-2