Sáàmù 52:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò yìn ọ títí fún ohun tí ó ti ṣe;èmí ní ìrètí nínú orúkọ Rẹ, nítorí orúkọ Rẹ dára.Èmi yóò yìn ọ́ níwájú àwọn ènìyàn mímọ́.

Sáàmù 52

Sáàmù 52:1-9