Sáàmù 52:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n èmi dàbí igi Ólífìtí ó gbilẹ̀ nínú ilé Ọlọ́run;Èmi gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ Ọlọ́run tí kì í kùnà láé àti láéláé.

Sáàmù 52

Sáàmù 52:1-9