Sáàmù 50:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ó ba ní ẹbọ ọrẹ ọpẹ́ bu ọláfún mi; kí ó sì tún ọ̀nà Rẹ̀ ṣekí èmi kí ó le fi ìgbàlà Ọlọ́run hàn án.”

Sáàmù 50

Sáàmù 50:21-23