Sáàmù 51:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sàánú fún mi, Ọlọ́run, gẹ́gẹ́ bíìdúró sinsin ìfẹ́ Rẹ̀,gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀ àánú Rẹ̀kí o sì pa gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi rẹ́.

Sáàmù 51

Sáàmù 51:1-5