Sáàmù 5:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n èmi, nípa títóbi àánú Rẹ̀,èmi yóò wá sínú ilé Rẹ̀;ní tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ ni èmi yóò tẹríbasí ìhà tẹ́ḿpìlì mímọ́ Rẹ̀.

Sáàmù 5

Sáàmù 5:5-12