Sáàmù 5:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tọ́ mi, Olúwa, nínú òdodo Rẹ,nítorí àwọn ọ̀ta mi,mú ọ̀nà Rẹ tọ́ níwájú mi.

Sáàmù 5

Sáàmù 5:3-12