Sáàmù 5:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò pa àwọn tí ń ṣe èké run;apani àti ẹni ẹ̀tàn ènìyànni Olúwa yóò kórìíra.

Sáàmù 5

Sáàmù 5:3-11