Sáàmù 43:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ran ìmọ́lẹ̀ àti òtítọ́ Rẹ jáde,jẹ́ kí wọn ó máa dààbò bò mí;jẹ́ kí wọn mú mi wá sí òkè mímọ́ Rẹ,sí ibi tí ìwọ ń gbé.

Sáàmù 43

Sáàmù 43:1-5