Sáàmù 43:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ni Ọlọ́run ibi agbára mi.Èéṣe tí ìwọ fi kọ̀ mi sílẹ̀?Èéṣe tí èmi yóò máa rìn nínú ìbìnújẹ́,nítorí ìnilára lọ́dọ̀ àwọn ọ̀tá?

Sáàmù 43

Sáàmù 43:1-4