Sáàmù 43:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ní èmi o lọ sí ibi pẹpẹ Ọlọ́run,sí Ọlọ́run ayọ̀ mí àti ìdùnnú mi,èmi yóò yin ọ pẹ̀lú dùùrù,ìwọ Ọlọ́run, Ọlọ́run mi.

Sáàmù 43

Sáàmù 43:3-5