Sáàmù 42:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọ̀sán ní Olúwa ran ìfẹ́ Rẹ̀,àti ni àṣálẹ́ ni orin Rẹ̀ wà pẹ̀lú miàdúrà sí Ọlọ́run ayé mi.

Sáàmù 42

Sáàmù 42:7-11