Sáàmù 42:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ibú omi ń pe ibú ominípa híhó omi ṣíṣàn Rẹ̀gbogbo rírú omi àti bíbì omi Rẹ̀bò mí mọ́lẹ̀.

Sáàmù 42

Sáàmù 42:5-11