Sáàmù 42:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi wí fún Ọlọ́run àpátà mi,“Èéṣe tí ìwọ fi gbàgbé mi?Èéṣe tí èmi o fi máa rìn nínú ìbànújẹ́,nítorí ìnilára ọ̀ta?”

Sáàmù 42

Sáàmù 42:7-11