Sáàmù 39:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Mo wí pé,èmi yóò ṣọ́ ọ̀nà mikí èmi kí ó má fi ahọ́n mi ṣẹ̀èmi yóò fi ìjánu kó ara mi ní ẹnuníwọ̀n ìgbà tí ènìyàn búburúbá ń bẹ ní iwájú mi.

2. Mo fi ìdákẹ́ ya odi;mo tilẹ̀ pa ẹnu mi mọ́kúrò nínú ọ̀rọ̀ rere;ìbànújẹ́ mi sì pọ̀ síi.

3. Àyà mi gbóná ní inú mi,nígbà tí mo ń ṣàṣàrò,ina ràn;nígbà náà ni mo fi ahọ́n mi sọ̀rọ̀.

4. Olúwa,jẹ́ kí èmi kí ó mọ òpin mi,àti ìwọ̀n ọjọ́ mi, bí ó ti ríkí èmi kí o le mọ ìgbà tí mó ní níhìn-ín.

Sáàmù 39