Sáàmù 39:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àyà mi gbóná ní inú mi,nígbà tí mo ń ṣàṣàrò,ina ràn;nígbà náà ni mo fi ahọ́n mi sọ̀rọ̀.

Sáàmù 39

Sáàmù 39:1-11