Sáàmù 39:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo wí pé,èmi yóò ṣọ́ ọ̀nà mikí èmi kí ó má fi ahọ́n mi ṣẹ̀èmi yóò fi ìjánu kó ara mi ní ẹnuníwọ̀n ìgbà tí ènìyàn búburúbá ń bẹ ní iwájú mi.

Sáàmù 39

Sáàmù 39:1-4