Sáàmù 29:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ fi fún Olúwa, ẹ̀yin ìran ọ̀run,Ẹ fi fún Olúwa, ògo àti agbára.

2. Fi fún Olúwa, àní ògo orúkọ Rẹ̀;sin Olúwa nínú ẹwà ìwà mímọ́.

Sáàmù 29