Sáàmù 27:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé ní ìgbà ìpọ́njúòun yóò pa mí mọ́ nínú àgọ́ Rẹ̀;níbi ìkọ̀kọ̀ àgọ́ Rẹ̀ ni òun yóò pa mí mọ́;yóò sì gbé mi sókè lórí àpáta.

Sáàmù 27

Sáàmù 27:1-13