Sáàmù 27:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun kan ni mo bèèrè nípasẹ̀ Olúwa,òun ni èmi yóò máa wá kiri:kí èmi kí ó le wà ní ilé Olúwaní ọjọ́ ayé mi gbogbo,kí èmi: kí ó le kíyèsí ẹwà Olúwa,kí èmi kí ó sì máa wà ní tẹ́ḿpìlì Rẹ.

Sáàmù 27

Sáàmù 27:2-11