Sáàmù 27:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìsinsin yìí a ti gbé orí mi sókèga ju ti àwọn ọ̀tá a mi lọ tí ó yí mí ká;èmi yóò rúbọ nínú àgọ́ Rẹ ẹbọ ariwo àti ti ayọ̀;èmi yóò kọrin àní orin dídùn sí Olúwa.

Sáàmù 27

Sáàmù 27:1-8