Sáàmù 26:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe gbá mi dànù pẹ̀lú àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀,tàbí ẹ̀mí mi pẹ̀lú àwọn ọkùnrin tí òǹgbẹ ẹ̀jẹ̀ ń gbẹ,

Sáàmù 26

Sáàmù 26:6-11