Sáàmù 26:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áà Olúwa, èmí ń fẹ́ ilé Rẹ ní bi tí ìwọ ń gbé,àní níbi tí àgọ́ ọlá Rẹ̀ wà.

Sáàmù 26

Sáàmù 26:5-12