Sáàmù 26:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn tí ọwọ́ wọn kún fún ìwà ibi,tí ọwọ́ ọ̀tún wọn kún fún àbẹ̀tẹ́lẹ̀.

Sáàmù 26

Sáàmù 26:9-12