Sáàmù 19:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìlànà Olúwa tọ̀nà,ó ń fi ayọ̀ fún ọkàn.àṣẹ Olúwa ní mímọ́,ó ń fi ìmọ́lẹ̀ fún ojú.

Sáàmù 19

Sáàmù 19:1-12