Sáàmù 19:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbẹ̀rù Olúwa mọ́,ó ń faradà títí láéláé.Ìdájọ́ Olúwa dájúòdodo ni gbogbo wọn.

Sáàmù 19

Sáàmù 19:1-11