Sáàmù 19:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pípé ni òfin Olúwa,ó ń yí ọkàn padà.ẹ̀rí Olúwa dánilójú,ó sọ òpè di ọlọ́gbọ́n.

Sáàmù 19

Sáàmù 19:4-12