Sáàmù 19:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìjáde lọ Rẹ̀ ni láti òpin ọ̀run wáàti àyíká Rẹ̀ sì dé ìpínlẹ̀ Rẹ̀;kò sì sí ohun tí ó pamọ́ kúrò nínú oore Rẹ̀.

Sáàmù 19

Sáàmù 19:1-10