Sáàmù 19:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ti o dàbí ọkọ ìyàwó tí ó ń jáde ti yàrá Rẹ̀ wáÒun yọ bí alágbára ọkùnrin tí o ń sáré ìje.

Sáàmù 19

Sáàmù 19:1-14